Загрузка страницы

Gbat' agbara Olorun de(Ran Agbara Oluwa) CAC Hymn 366 by Anointed Elias Ijaopo

Gbat' agbara Olorun de

Li ojo Pentikosti

Sa ifoju sona pari

Tori won ri Emi gba
Chorus

Ran agbara Oluwa

Ran agbara Oluwa

Ran agbara Oluwa

Ki o si baptis wa
Ela 'han ina ba le won

Won si wasu oro na

Opolopo enia gbagbo

Won yi pada s' Olorun

Ran agbara Oluwa
A nwona fun Emi Mimo

Gbogbo wa f'ohun sokan

Mu 'leri na se Oluwa

Ti a se nin'oro Re

Ran agara Oluwa
Jo fi agbara Re kun wa

Fun wa ni 'bukun t'a nfe

Fi ogo Re kun okan wa

B'a ti nfi' bagbo bebe

Ran agbara Oluwa

Видео Gbat' agbara Olorun de(Ran Agbara Oluwa) CAC Hymn 366 by Anointed Elias Ijaopo канала Anointed Elias Ijaopo
Показать
Комментарии отсутствуют
Введите заголовок:

Введите адрес ссылки:

Введите адрес видео с YouTube:

Зарегистрируйтесь или войдите с
Информация о видео
7 февраля 2020 г. 18:09:20
00:04:36
Яндекс.Метрика